Àwọn Ọba Keji 11:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Jehoiada alufaa mú kí Joaṣi ọba ati àwọn eniyan dá majẹmu pẹlu OLUWA pé àwọn yóo jẹ́ tirẹ̀; ó sì tún mú kí àwọn eniyan náà bá ọba dá majẹmu.

Àwọn Ọba Keji 11

Àwọn Ọba Keji 11:11-21