Àwọn Ọba Keji 11:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọmọ ogun sì dúró pẹlu ohun ìjà lọ́wọ́ wọn láti ìhà gúsù ilé náà títí dé ìhà àríwá rẹ̀, wọ́n yí pẹpẹ ati ilé náà ká.

Àwọn Ọba Keji 11

Àwọn Ọba Keji 11:5-19