Àwọn Ọba Keji 10:3 BIBELI MIMỌ (BM)

ẹ fi èyí tí ó bá jẹ́ akọni jùlọ lára àwọn ọmọ ọba sí orí oyè, ẹ sì múra láti jà fún ilẹ̀ oluwa yín.”

Àwọn Ọba Keji 10

Àwọn Ọba Keji 10:1-7