Àwọn Ọba Keji 10:29 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn Jehu tẹ̀lé ẹ̀ṣẹ̀ Jeroboamu, ọmọ Nebati, tí ó mú kí Israẹli bọ ère ẹgbọ̀rọ̀ mààlúù, tí wọ́n fi wúrà ṣe, tí ó wà ní Bẹtẹli ati Dani.

Àwọn Ọba Keji 10

Àwọn Ọba Keji 10:23-36