Àwọn Ọba Keji 1:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n dáhùn pé, “Ọkunrin náà wọ aṣọ tí wọ́n fi awọ ẹranko ṣe, ó sì di àmùrè awọ mọ́ ẹ̀gbẹ́.”Ọba dáhùn pé, “Elija ará Tiṣibe ni.”

Àwọn Ọba Keji 1

Àwọn Ọba Keji 1:1-16