Àwọn Ọba Keji 1:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ lọ sọ fún ọba pé, báyìí ni OLUWA wí, ‘O kò ní sàn ninu àìsàn náà, kíkú ni o óo kú.’ ”Elija sì ṣe gẹ́gẹ́ bí OLUWA ti pàṣẹ fún un.

Àwọn Ọba Keji 1

Àwọn Ọba Keji 1:1-13