Àwọn Ọba Keji 1:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Ahasaya ọba ṣubú láti orí òkè ilé rẹ̀ ní Samaria, ó sì farapa pupọ. Nítorí náà ni ó ṣe rán oníṣẹ́ lọ bèèrè lọ́wọ́ Baalisebubu, oriṣa Ekironi, bóyá òun yóo sàn ninu àìsàn náà tabi òun kò ní sàn.

Àwọn Ọba Keji 1

Àwọn Ọba Keji 1:1-8