Àwọn Adájọ́ 9:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní àkókò kan, àwọn igi oko kó ara wọn jọ pé wọ́n fẹ́ ọba, wọ́n lọ sọ́dọ̀ igi Olifi, wọ́n wí fún un pé kí ó máa jọba lórí wọn.

Àwọn Adájọ́ 9

Àwọn Adájọ́ 9:4-10