Àwọn Adájọ́ 9:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo àwọn ará ìlú Ṣekemu ati ti Bẹtimilo bá para pọ̀, wọ́n fi Abimeleki jọba níbi igi Oaku kan tí ó wà níbi ọ̀wọ̀n tí ó wà ní Ṣekemu.

Àwọn Adájọ́ 9

Àwọn Adájọ́ 9:1-10