Àwọn Adájọ́ 9:43 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó kó àwọn ọkunrin tí wọ́n wà pẹlu rẹ̀, ó pín wọn sí ìsọ̀rí mẹta, wọ́n sì ba níbùba ninu pápá. Bí ó ti rí i pé àwọn eniyan náà ń jáde bọ̀ láti inú ìlú, ó gbógun tì wọ́n, ó sì pa wọ́n.

Àwọn Adájọ́ 9

Àwọn Adájọ́ 9:33-48