Àwọn Adájọ́ 9:34 BIBELI MIMỌ (BM)

Abimeleki ati àwọn ọkunrin tí wọ́n wà pẹlu rẹ̀ bá gbéra ní òru, wọ́n lọ ba níbùba lẹ́gbẹ̀ẹ́ Ṣekemu, ní ìsọ̀rí mẹrin.

Àwọn Adájọ́ 9

Àwọn Adájọ́ 9:30-42