Àwọn Adájọ́ 9:31 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó ranṣẹ sí Abimeleki ní Aruma, ó ní, “Gaali, ọmọ Ebedi, ati àwọn arakunrin rẹ̀ ti dé sí Ṣekemu, wọn kò sì ní gbà fún ọ kí o wọ ibí mọ́.

Àwọn Adájọ́ 9

Àwọn Adájọ́ 9:27-32