Àwọn Adájọ́ 9:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn eniyan ìyá rẹ̀ bá sọ gbogbo ọ̀rọ̀ yìí ní etígbọ̀ọ́ gbogbo àwọn ará ìlú Ṣekemu, wọn sì gbà láti tẹ̀lé Abimeleki tayọ̀tayọ̀. Wọ́n ní, “Arakunrin wa ni Abimeleki jẹ́.”

Àwọn Adájọ́ 9

Àwọn Adájọ́ 9:1-5