Àwọn Adájọ́ 9:29 BIBELI MIMỌ (BM)

Ìbá ṣe pé ìkáwọ́ mi ni àwọn eniyan yìí wà, ǹ bá yọ Abimeleki kúrò lórí oyè. Ǹ bá sọ fún Abimeleki pé kí ó lọ wá kún àwọn ọmọ ogun rẹ̀ kí ó jáde wá bá mi jà.”

Àwọn Adájọ́ 9

Àwọn Adájọ́ 9:21-37