Àwọn Adájọ́ 9:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Jotamu bá sá lọ sí Beeri, ó sì ń gbé ibẹ̀, nítorí ó bẹ̀rù Abimeleki arakunrin rẹ̀.

Àwọn Adájọ́ 9

Àwọn Adájọ́ 9:19-24