Àwọn Adájọ́ 9:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn lónìí, ẹ dìde sí ìdílé baba mi, ẹ sì pa aadọrin àwọn ọmọkunrin rẹ̀ lórí òkúta, ẹ wá fi Abimeleki, ọmọ iranṣẹbinrin rẹ̀ jọba lórí ìlú Ṣekemu, nítorí pé ó jẹ́ ìbátan yín.

Àwọn Adájọ́ 9

Àwọn Adájọ́ 9:15-28