Àwọn Adájọ́ 8:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ará Efuraimu bèèrè lọ́wọ́ Gideoni pé, “Irú kí ni o ṣe yìí, tí o kò pè wá, nígbà tí o lọ gbógun ti àwọn ara Midiani?” Wọ́n bá bẹ̀rẹ̀ sí sọ̀rọ̀ sí i pẹlu ibinu.

Àwọn Adájọ́ 8

Àwọn Adájọ́ 8:1-7