Àwọn Adájọ́ 7:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn tí wọ́n fi ọwọ́ bomi, tí wọ́n sì fi ahọ́n lá a bí ajá jẹ́ ọọdunrun (300), gbogbo àwọn yòókù ni wọ́n kúnlẹ̀ kí wọ́n tó mu omi.

Àwọn Adájọ́ 7

Àwọn Adájọ́ 7:5-16