Àwọn Adájọ́ 7:23 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọmọ ogun Israẹli pe àwọn ọkunrin Israẹli jáde láti inú ẹ̀yà Nafutali, ati ti Aṣeri ati ti Manase, wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ sí lé àwọn ará Midiani lọ.

Àwọn Adájọ́ 7

Àwọn Adájọ́ 7:22-25