Àwọn Adájọ́ 7:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Olukuluku wọn dúró sí ààyè wọn yípo àgọ́ náà, gbogbo àwọn ọmọ ogun Midiani bá bẹ̀rẹ̀ sí sá káàkiri, wọ́n ń kígbe, wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ sí sá lọ.

Àwọn Adájọ́ 7

Àwọn Adájọ́ 7:16-23