Àwọn Adájọ́ 7:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹnìkejì rẹ̀ dá a lóhùn, ó ní, “Èyí kì í ṣe ohun mìíràn, bíkòṣe idà Gideoni, ọmọ Joaṣi, ọ̀kan ninu àwọn ọmọ Israẹli. Ọlọrun ti fi Midiani ati gbogbo ọmọ ogun rẹ̀ lé e lọ́wọ́.”

Àwọn Adájọ́ 7

Àwọn Adájọ́ 7:12-15