Àwọn Adájọ́ 7:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ará ilẹ̀ Midiani ati ti Amaleki ati àwọn ará ilẹ̀ tí ó wà ní ìlà oòrùn pọ̀ nílẹ̀ lọ bí eṣú àwọn ràkúnmí wọn kò níye, wọ́n pọ̀ bí iyanrìn etí òkun.

Àwọn Adájọ́ 7

Àwọn Adájọ́ 7:10-16