Àwọn Adájọ́ 6:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo gbà yín lọ́wọ́ àwọn ará Ijipti, ati gbogbo àwọn tí wọn ń ni yín lára. Mo lé wọn jáde fún yín, mo sì fi ilẹ̀ wọn fun yín.

Àwọn Adájọ́ 6

Àwọn Adájọ́ 6:3-15