Àwọn Adájọ́ 6:40 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọlọrun tún ṣe bẹ́ẹ̀ ní alẹ́ ọjọ́ náà, nítorí pé, orí irun yìí nìkan ṣoṣo ni ó gbẹ, ìrì sì sẹ̀ sí gbogbo ilẹ̀.

Àwọn Adájọ́ 6

Àwọn Adájọ́ 6:38-40