Àwọn Adájọ́ 6:34 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn Ẹ̀mí Ọlọrun bà lé Gideoni, Gideoni bá fọn fèrè ogun, àwọn ọmọ Abieseri bá pe ara wọn jáde wọ́n bá tẹ̀lé e.

Àwọn Adájọ́ 6

Àwọn Adájọ́ 6:25-39