Àwọn Adájọ́ 6:32 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, láti ọjọ́ náà lọ ni wọ́n ti ń pe Gideoni ní Jerubaali, ìtumọ̀ rẹ̀ ni pé, “Ẹ jẹ́ kí Baali bá a jà fúnra rẹ̀,” nítorí pé ó wó pẹpẹ rẹ̀ lulẹ̀.

Àwọn Adájọ́ 6

Àwọn Adájọ́ 6:28-38