Àwọn Adájọ́ 6:27 BIBELI MIMỌ (BM)

Gideoni mú mẹ́wàá ninu àwọn iranṣẹ rẹ̀, ó sì ṣe bí OLUWA ti ní kí ó ṣe, ṣugbọn kò lè ṣe é lọ́sàn-án, nítorí ẹ̀rù àwọn ará ilé ati àwọn ará ìlú rẹ̀ ń bà á, nítorí náà lóru ni ó ṣe é.

Àwọn Adájọ́ 6

Àwọn Adájọ́ 6:25-35