Àwọn Adájọ́ 6:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Gideoni bá tẹ́ pẹpẹ kan níbẹ̀ fún OLUWA, ó pe orúkọ rẹ̀ ní “OLUWA ni Alaafia.” Pẹpẹ náà wà ní Ofira ti ìdílé Abieseri títí di òní olónìí.

Àwọn Adájọ́ 6

Àwọn Adájọ́ 6:23-32