Àwọn Adájọ́ 6:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà náà ni Gideoni tó mọ̀ pé angẹli OLUWA ni, ó bá dáhùn pé, “Yéè! OLUWA Ọlọrun, mo gbé! Nítorí pé mo ti rí angẹli OLUWA lojukooju.”

Àwọn Adájọ́ 6

Àwọn Adájọ́ 6:16-28