Àwọn Adájọ́ 6:16 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA dá a lóhùn, ó ní, “N óo wà pẹlu rẹ, o óo sì run àwọn ará Midiani bí ẹni pé, ẹyọ ẹnìkan péré ni wọ́n.”

Àwọn Adájọ́ 6

Àwọn Adájọ́ 6:14-21