Àwọn Adájọ́ 5:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ìgbà ayé Ṣamgari, ọmọ Anati,ati nígbà ayé Jaeli, ọ̀wọ́ èrò kò rin ilẹ̀ yìí mọ́,àwọn arìnrìnàjò sì ń gba ọ̀nà kọ̀rọ̀.

Àwọn Adájọ́ 5

Àwọn Adájọ́ 5:4-7