Àwọn Adájọ́ 5:31 BIBELI MIMỌ (BM)

Bẹ́ẹ̀ ni kí gbogbo àwọn ọ̀tá rẹ ṣègbé, OLUWA;ṣugbọn bí oòrùn ti máa ń fi agbára rẹ̀ ràn,bẹ́ẹ̀ ni kí àwọn ọ̀rẹ́ rẹ máa tàn.Ilẹ̀ náà sì wà ní alaafia fún ogoji ọdún.

Àwọn Adájọ́ 5

Àwọn Adájọ́ 5:27-31