Àwọn Adájọ́ 5:26 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó na ọwọ́ mú èèkàn àgọ́,ó na ọwọ́ ọ̀tún rẹ̀, ó he òòlù àwọn alágbẹ̀dẹ,ó kan Sisera mọ́lẹ̀ lẹ́ẹ̀kan ṣoṣo;ó fọ́ ọ lórí,ó lù ú ní ẹ̀bá etí,ó sì fọ́ yángá-yángá.

Àwọn Adájọ́ 5

Àwọn Adájọ́ 5:24-31