Àwọn Adájọ́ 4:13 BIBELI MIMỌ (BM)

ó kó ẹẹdẹgbẹrun (900) kẹ̀kẹ́ ogun onírin rẹ̀ jọ, ó sì pe àwọn ọmọ ogun rẹ̀ jọ láti Haroṣeti-ha-goimu títí dé odò Kiṣoni.

Àwọn Adájọ́ 4

Àwọn Adájọ́ 4:10-19