Àwọn Adájọ́ 3:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn nígbà tí wọ́n kígbe pé OLUWA, OLUWA gbé olùdáǹdè kan dìde fún wọn tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Otinieli, ọmọ Kenasi, àbúrò Kalebu, òun ni ó gbà wọ́n kalẹ̀.

Àwọn Adájọ́ 3

Àwọn Adájọ́ 3:1-18