Àwọn Adájọ́ 21:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ó di ọjọ́ keji, àwọn eniyan náà dìde ní òwúrọ̀ kutukutu, wọ́n tẹ́ pẹpẹ kan, wọ́n sì rú ẹbọ sísun ati ẹbọ alaafia níbẹ̀.

Àwọn Adájọ́ 21

Àwọn Adájọ́ 21:1-10