Àwọn Adájọ́ 21:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọmọ Israẹli bá kúrò níbẹ̀, gbogbo wọ́n sì pada sí ilẹ̀ wọn, olukuluku pada lọ sí ìlú rẹ̀, sí ààrin ẹbí rẹ̀.

Àwọn Adájọ́ 21

Àwọn Adájọ́ 21:14-25