Àwọn Adájọ́ 21:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn àgbààgbà ìjọ eniyan náà bá bèèrè pé, “Níbo ni a óo ti rí aya fún àwọn tí wọ́n ṣẹ́kù, níwọ̀n ìgbà tí a ti pa àwọn obinrin ẹ̀yà Bẹnjamini run.”

Àwọn Adájọ́ 21

Àwọn Adájọ́ 21:11-20