Àwọn Adájọ́ 21:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Ni ìjọ eniyan bá ranṣẹ sí àwọn ará Bẹnjamini tí wọ́n wà níbi àpáta Rimoni, pé ìjà ti parí, alaafia sì ti dé.

Àwọn Adájọ́ 21

Àwọn Adájọ́ 21:7-15