Àwọn Adájọ́ 20:41 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọmọ Israẹli bá yipada sí wọn, ìdààmú sì bá àwọn ọmọ Bẹnjamini nítorí wọ́n rí i pé ewu ńlá súnmọ́ tòsí.

Àwọn Adájọ́ 20

Àwọn Adájọ́ 20:37-45