Àwọn Adájọ́ 20:34 BIBELI MIMỌ (BM)

Ni ẹgbaarun (10,000) àṣàyàn àwọn jagunjagun ninu àwọn ọmọ Israẹli bá gbógun ti ìlú Gibea. Ogun náà gbóná gidigidi ṣugbọn àwọn ará Bẹnjamini kò mọ̀ pé ewu ńlá súnmọ́ tòsí wọn.

Àwọn Adájọ́ 20

Àwọn Adájọ́ 20:24-41