Àwọn Adájọ́ 20:30 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọmọ Israẹli tún gbógun ti àwọn ọmọ Bẹnjamini ní ọjọ́ kẹta, wọ́n tò yípo Gibea bíi ti iṣaaju.

Àwọn Adájọ́ 20

Àwọn Adájọ́ 20:27-39