Àwọn Adájọ́ 20:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Láì ka àwọn tí àwọn ará Bẹnjamini náà kó jọ, àwọn ọmọ Israẹli kó ogún ọ̀kẹ́ (400,000) jagunjagun tí wọn ń lo idà jọ.

Àwọn Adájọ́ 20

Àwọn Adájọ́ 20:11-27