Àwọn Adájọ́ 20:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọmọ Bẹnjamini bá kó ara wọn jọ láti gbogbo ìlú ńláńlá, wọ́n wá sí Gibea láti gbógun ti àwọn ọmọ Israẹli.

Àwọn Adájọ́ 20

Àwọn Adájọ́ 20:12-22