Àwọn Adájọ́ 2:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Joṣua tú àwọn ọmọ Israẹli ká, olukuluku wọn pada lọ sí orí ilẹ̀ wọn, wọ́n sì ń gbé ibẹ̀.

Àwọn Adájọ́ 2

Àwọn Adájọ́ 2:1-16