Àwọn Adájọ́ 2:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Angẹli OLUWA sọ ọ̀rọ̀ yìí fún gbogbo àwọn ọmọ Israẹli, wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí sọkún tẹ̀dùntẹ̀dùn.

Àwọn Adájọ́ 2

Àwọn Adájọ́ 2:1-10