Àwọn Adájọ́ 2:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà inú a bí OLUWA sí àwọn ọmọ Israẹli, a sì wí pé, “Àwọn eniyan wọnyi ti da majẹmu tí mo pa láṣẹ fún àwọn baba wọn, wọn kò sì fetí sí òfin mi.

Àwọn Adájọ́ 2

Àwọn Adájọ́ 2:18-23