Àwọn Adájọ́ 19:29 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ó dé ilé, ó mú ọ̀bẹ, ó gé òkú obinrin yìí sí ọ̀nà mejila, ó sì fi wọ́n ranṣẹ sí gbogbo agbègbè Israẹli.

Àwọn Adájọ́ 19

Àwọn Adájọ́ 19:25-30