Àwọn Adájọ́ 19:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ó yá, ọkunrin arúgbó kan ń ti oko bọ̀ ní alẹ́; ará agbègbè olókè Efuraimu ni, ṣugbọn Gibea ni ó ń gbé. Àwọn ẹ̀yà Bẹnjamini ni wọ́n ń gbé ìlú náà.

Àwọn Adájọ́ 19

Àwọn Adájọ́ 19:11-22