Àwọn Adájọ́ 19:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí wọ́n súnmọ́ Jebusi, ilẹ̀ ti ń ṣú lọ, iranṣẹ rẹ̀ sọ fún un pé, “Jẹ́ kí á dúró ní ìlú àwọn ará Jebusi yìí kí á sì sùn níbẹ̀ lónìí.”

Àwọn Adájọ́ 19

Àwọn Adájọ́ 19:4-14